Tope Alabi - Yes And Amen Download Mp3
Download Song


Lyrics - Yes and Amen

Amin Ase ida a lamo o

Eni ti o ni a padanu

Iba o to to olu Imo o

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o

Amin aseda

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o

Eni ti o ni o, ko ni nkankan

(Ko ni nkankan)

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o

Oooooooo

Eni ti o ni o, ko ni nkankan

E ko ni nkankan o

Mo wa ri foba to ni di da aiye eeee

Ibare mare e, oni gbede orun

Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo

Bo ti doyi kato

Iba oni mo to ga ju ee

Baba ni baba se

Amin ase ida mo gbe ba fun

Amin ase ida la mo o

Eni ti o ni o ke

Eni ti o ni a padanu

Adanu nla lo pa laye, lorun

Iba o toto olu imo

A ton ton to, mo ri ba, mori ba o

Eni ti o ni o ko ni nkankan

Ko ni nkankan

Eni ti o ni o ko ni nkankan o

E ma ni penre labo

Eni ti o ni o, ko ni nkankan

Ko ni kini nkan lagbon

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o

O tan fun laiye lorun o

Eni ti o ni o Ee

Ko ni nkankan

O da okun, O da oosa

Alara to fi omi se osho

Iwo to mo ibi eja gba do odo

Majemu to bu ko ja okun

Iyanrin te ka aiye

O da okunkun biri mu

Oga imole oo

Oju orun o ni ilekun oo

Ogbe bi mejeeji, lai rin irin ajo

O mu eda gba inu eda waiye

Ibi emi ngba lo ba, eni kan o mo

Ajulo o eni ti o wa o

Ko le mo nkankan

Eni ti o wa ke o

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o

Ko ri nkankan o o

Eni ti o ni o, ko ni nkankan

Afoju san ju oni to hun lo mo gba

Eni ti o ni o, ko ni nkankan

Ee

Eni ti o ni o, ko ni nkankan

Eee

Majemu alai lepin n lo je

Ijinle alaile tun wo

Irawo nyo lailai lo nka beni

Osupa nse atokun to ba dale beni o

Ibi gbogbo la n ti mi ri beni

O to lo fara da orun saiye beni o

O se ojo otun so da eran beni

Osuwon bi oye, otun sotutu beni o

Eranko Igbo won lo su a beni

Eweko, ewebe igi iyen o se sawa ri na

Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o

Eni ti o ri se e, ko ri nkan

Eni ti o ri se e, ko ri nkankan

Ko da ko ri ra e pa be ni

Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o

Ooo

Eni ti o ri se e, ko ri nkankan...

Beat...

Ose mi da bi ohun, opin mi ni ipin

Ti ko Jo ti eni keji

Mi o la le hu, emi ni ami aseda latorun

Adagbeyin ni mi o wa fi mi joba

Ohun gbogbo ti o ti ko da

Odami ofunmi ni re

Emi ni beeni, ase olodumare ni

Amin lohun, emi lami

Ayanmo ogo, Ogun mi ni

Eda emi lo fi se ranse mi

Akori Iran mi, oju ogo re ni

Mo ni imi ye re ninu

Eni o ri mi, ko ri nkankan

Eee Eni ti o ri mi

Ko ri nkankan.

Eni ti o ri mi

Ko rise olorun wo

E Eni ti o ri mi ke, ko ri nkan

Eni ti o ri mi

Ko ri nkankan o

E o foju

Eni ti o ri mi, ko rise olorun wo

Ko ri olodumare, oda mi bi ohun ni

Eni ti o ri mi, ko ri nkankan

Eni ti o ri mi, ko ri se olorun wo

Ooooooo

Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o

Eni ti o ri mi, ko ri se olorun wo

Eni ti o ri mi ko ri nkankan

Ami lawa je, si Iwo amin

Beni ire loje ki aiye wa o

Olorun la min

Amin lon famin wa han

Aiye, atorun lamin yen o

Aseda ni amin

Oro re lo je ki a ma wa

Olorun la min

Amin, Amin, Amin, Amin o


Join our WhatsApp Group for New Songs Updates


Post a Comment

Previous Post Next Post