NewMusicAlert: ATILEYIN MI - Oluwafunmilayo Awopetu FUNMIPRAISE | Gospelwifi.com
A Nigerian Gospel Music minister, Songwriter and a praise machine and worshipper, oluwafunmilayo Awopetu FUNMIPRAISE drops a single tagged "ATILEYIN MI" (MY PILLAR/MY BACK BONE) in English
Rumerating over the challenges and storms faced so far, and seeing the mightiness of God as the only one who didn't forsake.God have being so faithful and have been the Father for the Fatherless.
When the challenges of this world give you many reasons to be discouraged or depressed,He is a caring Father whom will never forsake you.
When the disciples were in the middle of storm,they called on the MASTER and He calm the storm.
ATILEYIN MI is a song of A Praise and appreciations to the almighty God.
He,who appreciate deserves another.... PRAISE THE ATILEYIN WA
Download, Listen & Share;
Lyrics : ATILEYIN MI
Oluwa wa otobi/2*
Titobi re ko Iafiwe ooo
Oluwa wa otobi
Gba ti igbi aye yi to yimika
Gba ti iji yen fe Lele bi enipe mofe subu
Iwo ni agbara mi iwo loba ti Momo
Baba alatileyin mi ese ooooo
Chorus: EYIN naani,Eyin ni Oluwa
ATILEYIN Mi,agbara,atolugbala mi,
baba olutoju mi,ese gbogbo igba,
dansaki re, Baba mi
VC1: itoju re koni ye Lori aye mi
Jije,mimu, Lilo, Bibo, melo mo fe rooo
Anu to fi baye mi Rin,
kolosuwon dansaki re Baba mi/2*
Chorus;
Talodabire olorun mi,
ninu gbogbo orisa kekeke taye nkepe,
eyin naani,
eyin loba taye nwari fun oooo,
kabiyesi re olorun to nje Emi ni,
emi ni,
emi ni oooo,
emi mase beeru,arugbo ojo oba taye nwari fun ni,
eyin ni ATILEYIN Mi ni gbogbo igba,
Momo riri re Baba ese ooooo
Iwo ni yin to si oloore mi,
oloore ofe julo,agbani lagbatan,
alabo wa,awoni ma gbeje oo,
iyin ye ooo atobi julo,ebo ope,
ebo ope mi maare ooo,
si olutunu orun to gaa julo,
iwo loye lati gba gbogbo ogo,
tewo gbope wa tewo gboyin wa
Iba masepe oluwa to wa Nipa tiwa,
kini awa iba ma Wii nigba ti ota gbogun de,
eyin ni oluso wa, eyin loba to pawa mo oooo,
ese alanu wa ni gbogbo ona oooo,
tire ni ogo ooo,
tire ni ola ati iyin,tire ni ope,
tire ni ogo tire ni ola ooo,
abanise olugbe orimi soke,
dansaki re, Daddy mi oooo
Call: Emi omo re mo yin ooo logo baba ese
Resp: Emi omo re moyin ooo logo Baba ese
Call: olutoju mi baba mo gbe o gaa aaa
Call:Jije mimu Lilo bibo oma tope ojope loo
Call: I appreciate your Faithfulness over my life thank you
Call: Kiki da ope ooo,iyin lo to si oo baba mi
Call: Your praise/2* will never seize in my mouth
Call: Titi lailai ooo,titi lailai lope re lenu mi
Call: Emi omo re moyin ooo logo ese ese ooo
Call:Maafijo gbe o gaa maaforin gbe o gaaa
Call: Oti mo mi Lara lati mayin oooo
ALATILEYIN MI
Post a Comment